News

Awọn to ba BBC Yoruba sọrọ lorii isẹlẹ naa salaye pe ojo naa bẹrẹ lọjọ Ẹti to kọja, ko si da titi di ọjọ Abamẹta.